
GBO ‘gbe ayo! Oluwa de
1. GBO ‘gbe ayo! Oluwa de, Jesu t’ a seleri; Ki gbogbo okan mura de, K’ ohun mura ko ‘ rin 2. O de lati

1. GBO ‘gbe ayo! Oluwa de, Jesu t’ a seleri; Ki gbogbo okan mura de, K’ ohun mura ko ‘ rin 2. O de lati

1. ILU t’ o dara po l’ aiye; Betlehem’, ‘wo ta won yo; Ninu re l’ Oluwa ti wa Lati j’ oba Israel’. 2. Ogo

1. ODE, Kristi Oluwa, Lat’ ibugbe Re l’ orun, Lat’ ite alafia. O wa si aginju wa. 2. Alade Alana De, lati ru ‘ponju wa;

1. OJO ayo nlanla na de, Eyit’ araiye ti nreti; Nigbat’ Olugbala w’ aiye, Nigbat’ a bi ninu ara. 2. Olusagutan ni papa, Bi nwon

1. WO! gbogbo ile okunkun, Wo! okan mi, duro je; Gbogbo ileri ni o nso T’ ojo ayo t’o l’ ogo; Ojo Ayo! K’ owuro

1. GBO eda orun nkorin, “Ogo fun Oba t’ a bi.” “Alafia l’ aiye yi,” Olorun ba wa laja, Gbogbo eda, nde l’ ayo, Dapo

1. ONIGBAGBO, e bu s’ ayo! Ojo nla l’ eyi fun wa; K’ orun f’ ayo korin kikan, K’ igbo at’ odan gberin. E ho!

1. AYO kun okan wa loni A bi Omo Oba; Opo awon ogun orun, Nso t’ ibi Re loni: E yo, Olorun d’ enia, O

1. WA enyin oloto L’ ayo at’ isegun Wa kalo, wa kalo si Betlehem; Wa kalo wo o! Oba awon Angeli! E wa kalo juba

1. GBO ohun alore, Ji, ara, ji: Jesu ma fere, de, Ji, ara, ji Omo oru ni sun, Omo imole l’ enyin, Ti nyin l’
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar