
OLORUN l’ abo eni Re
1. OLORUN l’ abo eni Re, Nigba iji iponju de: K’ awa to se aroye wa, A! saw o t’ On t’ iranwo Re. 2.

1. OLORUN l’ abo eni Re, Nigba iji iponju de: K’ awa to se aroye wa, A! saw o t’ On t’ iranwo Re. 2.

1. YIN Olorun Oba wa, E ko orin ogo si, ‘Tor’ anu Re wa sibe, L’ ododo dajudaju. 2. Yin, n’tori t’ O da orun

1. IFE l’ Olorun: anu Re Mole s’ ona wa gbogbo; O ns’ ayo ji, O ndin ‘se ku: Ogbon nla ni olorun. 2. Iku

1. T’ OLORUN n’ ijoba gbogbo Oril-ede, e korin ‘yin: E so t’ ipa Re to tobi; Ola Re y’o m’ orin yin dun. 2.

1. ONA ara l’ Olorun wa Ngba sise Re l’ aiye; A nri ‘pase Re lor’ okun, O ngun igbi l’ esin. 2. Ona Re

1. OLUWA l’ O nso mi: Y’o te fe mi lorun: Niwon bi a ti je okan, Kil’ emi ‘ba tun fe? 2. O sin

1. SAJU wan so, Olorun, Fere ogun ti ro; Ninu papa isegun, N’ago Re l’ao ma gbe Anu re fun wa l’okun N’ipalemo f’ ogun

1. AYO b’ aiye: Oluwa de! K’ aiye gba Oba re; K’ okan gbogbo pes’ aye fun, Ki gbogb’ eda korin. 2. Ayo b’ aiye:

1. MA wo ‘le, Jesu t’ a nreti, T’a bi lati gba ni la! Gba wa low’ ese at’ eru, K’ a r’ isimi ninu

1. WO oju sanma ohun ni. Wo lila orun oro. Ji l’ oju orun, okan mi, Dide k’ o si ma sora; Olugbala Tun npada
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar