
MO mo p’Oludande mi mbe
1. “MO mo p’Oludande mi mbe;” Itunu nla l’eyi fun mi! O mbe, Enit’ o ku lekan; O mbe, Ori iye mi lai. 2. O

1. “MO mo p’Oludande mi mbe;” Itunu nla l’eyi fun mi! O mbe, Enit’ o ku lekan; O mbe, Ori iye mi lai. 2. O

1. EMI ‘bukun, bi afefe, Ni nfe sibit’ o wu; Awon, t’ iji re lu, bawo L’ okan won ti yo to! 2. O ntun

1. SO itan kanna fun mi, T’ ohun ni t’ a ko ri; Ti Jesu on ogo Re, Ti Jesu En ‘ ife, So itan

1. OLUWA, y’o ti pe to T’ Iwo o tun pada; Are fere mu wa tan, Bi a ti nw’ ona Re; Oluwa, y’o ti

1. JI, apa Olorun, k’ o ji, Gbe ‘pa Re wo, mi or’ ile; Ni sisin Re, je k’ aiye ri Isegun ise anu Re.

1. WO! Oluwa l’ awonsanma, O mbo l’ ogo’ l’ ola Re. Enit’ a pa fun elese Mbo pelu Angeli Re: Halleluya! Halleluya! Amin! 2.

1. OLORUN Olurapada, Mo ri ‘se mi nin’ oro Re, Ninu ‘gbe aiye Re nihin, Ofin f’ ara han gedegbe. 2. Iru otito on ‘tara

1. GBA t’ Olugbala w’ aiye, Anu j’ oba l’ okan Re, O nfi ibakedun han K’ O si gan enikeni. 2. Afoju Aro y’

1. A WON eye n’ ife, Kolokolo n’ iho, enia n’ ile: Eda n’ ib’ isimi Sugbon Jesu ko r’ ibi gborile. 2. Sibe O

1. KRIST’ ki ‘joba Re de, Ki ase Re bere; F’ opa-rin Re fo Gbogbo ipa ese. 2. Ijoba ife da, Ati t’ Alafia? Gbawo
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar