
OLUWA, Ob’ Alase
1. OLUWA, Ob’ Alase, A wole ni ese Re; Gbo igbe itara wa, Bi O ba r’ oju, ao ku. 2. O to, bi oko

1. OLUWA, Ob’ Alase, A wole ni ese Re; Gbo igbe itara wa, Bi O ba r’ oju, ao ku. 2. O to, bi oko

1. WO Oluwa oke, Ati abe ‘sanma; Mo do bale li ese Re, Mo nke fun anu Re. 2. Dari ‘were ji mi, Ese ti

1. IBU ife! O le je Pe a p’anu mo fun mi; Olorun mi ha le da ‘Binu ro fun elese? 2. Mo ti mb

1. OLUGBALA, lie se Re L’olote kan wole , O si f’igboiya gb’oju wo ‘Te anu Re loke. 2. Bi omije aro ba to San

1. MO ti mb’ese rin ti pe, Pin wa n’iya, Oluwa, Ore’parun ni tire, Gba mi Jesu, mo segbe. 2. ko s’ anfani ti mo

1. ALAIMO lie mi, Olorun Oluwa! Emi ha gbodo sunmo O T’ emi t’ eru ese? 2. Eru ese yii npa Okan buburu mi; Yio

1. ESE mi po bi irawo, B’ iyanrin let’ okun; Sugbon iyonu Olorun, O papoju be lo. 2. Manase, Paul on Magdalen, Iwo dariji won;

1. IWO low’ Enit’ ire nsan, Mo gb’ okan mi si O; N’ ibanuje at’ ise mi, Oluwa ranti mi. 2. ‘Gba mo kerora l’

1. OLUGBALA, gb’ ohun mi, Gb’ ohun mi, gb’ ohun mi; Mo wa sodo Re, gba mi, Nibi agbelebu. Emi se, sugbon O ku, Iwo

1. OLUWA, ma m’ oju kuro Lodo emi t’ o ny’ ile, Ti nsokun ese aiye mi, N’ ite anu ife Re. 2. Ma ba
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar