
JI, okan mi dide l’ ayo
1. JI, okan mi dide l’ ayo, Korin iyin Olugbala; Ola Re bere orin mi, ‘Seun ife Re ti po to! 2. O ri mo

1. JI, okan mi dide l’ ayo, Korin iyin Olugbala; Ola Re bere orin mi, ‘Seun ife Re ti po to! 2. O ri mo

1. A! mba le l’ egberun ahon. Fun ‘yin Olugbala, Ogo Olorun Oba mi, Isegun ore Re. 2. Jesu t’ O s’ eru wa d’

1. EYO, eyin mimo, e yin Ibukun; anu, igbala, Jesu oke nyin titi lai, D’ oju ko agbara iji. 2. Abo lowolowo ni se, Ife

1. JESU Od’-agutan, ‘Wo t’ O ta ‘je Re le, Lati gba wa lowo ‘parun, Gba iyin ailopin. 2. Si O, Om’-Olorun, L’ awon mimo

1. IRO t’ o dun ju orin, Fa mi l’ oruko Jesu, Gbogbo ‘reti okan mi Wa lor’ agbelebu Re. 2. Gbat’ o de, angel

1. IFE t’ o rekoja ero, T’ o se ‘lana rere, Fun ‘gbala enia, ki Adam T’ o mu isubu wa. 2. Olorun fe iran

1. IFE mi s’ ibi ti wa pe, Lai beru itiju, Titi mo fi r’ ohun titun, Ti o da mi duro. 2. Mo r’

1. KI sepe mo ko yan O, Oluwa, ko ri be, Okan mi iba ko O, Sugbon ‘Wo l’ o yan mi. 2. Kuro ninu

1. ODODO Re nikan laise t’ emi, L’ o le se isimi fun okan mi; Ife Re l’ o le mu k’ ifoiya lo, L’

1. EWE ti Oba orun, Korin didun b’ e ti nlo; Korin ‘yin t’ Olugbala, Ise Enit’ o l’ ogo. 2. E nlo sodo Olorun,
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar