
BENI, O bikita fun mi
1. BENI, O bikita fun mi, Pelu ike bi t’ egbon ; Beni, eru at’ ifoiya, Gbogbo re l’ O mba mi pin. 2. Beni,

1. BENI, O bikita fun mi, Pelu ike bi t’ egbon ; Beni, eru at’ ifoiya, Gbogbo re l’ O mba mi pin. 2. Beni,

1. JESU o ye ki nl’ ayo, Ti mba le gbekele O, Pe ogbon Re to to mi, Pe ore Re to pese, Pe ipa

1. BI Jesu ba fe mi, Bi mo ba je Tire, Nko ko ohun t’ ota le ro, Bi nwon tile n’ ipa. 2. Mo

1. ALAFIA pel’ Oluwa, A, ede wo l’ eyi! A f’ eje b’ elese la ‘ja, Oto ‘simi l’ eyi. 2. Ni iwa ati ni

1. OKAN mi nsimi, Oluwa; Ngo dupe, ngo ko ‘rin, Okan mi r’ ibi asiri Ti ire ti nsun wa. 2. Mo k’ ongbe orison

1. ENYIN t’ e fe Oluwa, E fi ayo nyin han, E jumo ko orin didun, E jumo ko orin didun, K’ e si y’

1. MO gbohun Jesu t’ o wipe, “Wa simi lodo Mi; Gbe ori re, ‘wo alare, Le okan aiya Mi.” Ninu are on ‘banuje, Ni

1. ISIN l’ o le fun wa li Ayo didun li aiye; Isin ni yio fun wa li Itunu nigba ba ku. 2. Lehin ‘ku

1. JESU, kiki ironu Re, Fi ayo kun okan; Sugbon k’ a ri O l’ o dun ju, K’ a simi lodo Re. 2. Enu

1. OLORUN ‘yanu! Ona kan Ti o dabi Tire ko si; Gbogb’ ogo ore-ofe Re L’ o farahan bi Olorun. Tal’ Olorun ti dariji, Ore
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar