
MO fe O n’gbagbogbo,
1. MO fe O n’gbagbogbo, Oluwa Olore Ko s’ ohun ti nfun ni L’ alafia bi Tire Mo fe O, a! mo fe O, Ni

1. MO fe O n’gbagbogbo, Oluwa Olore Ko s’ ohun ti nfun ni L’ alafia bi Tire Mo fe O, a! mo fe O, Ni

1. IFE lo to bayi? Ohun gbogbo pari, O ti pari gbogbo ise T’ O tori re w’ aiye. 2. Ohun ti Baba fe, Ni

1. MURA ebe, okan mi Jesu nfe gb’ adura re; O tip e k’ o gbadura, Nitorina yio gbo. 2. Lodo Oba n’ iwo mbo,

1. GBA aiye mi, Oluwa, Mo ya si mimo fun O; Gba gbogbo akoko mi, Ki nwon kun fun iyin Re. 2. Gba owo mi,

1. BI agbonrin ti nmi hele, S’ ipa odo omi; Beni okan mi nmi si O, Iwo Olorun mi. 2. Orungbe Re ngbe okan mi,

1. EMI ko mo ‘gbat’ Oluwa yio de, Lati mu mi lo si ile Re orun, Sugbon mo mo pe wiwa Re yio je ‘mole,

1. WA, iwo isun ibukun, Je ki nkorin ore Re: Odo anu ti nsan titi, Bere orin ‘yin kikan; Oluwa, ko mi l’ orun na

1. GBAT, a b’Oluwa rin N’nu ‘mole oro Re Ona wa yi o ti l’ogo to! ‘Gbat’ a ba nse f’e Re On y’o ma

1. AYO omo anu ti to! T’ o mo idariji: O nwip’ aiye ki se ‘le mi, Mo nwa ‘le mi s’ orun 2. Ilu

1. AYO awon ti to, T’ o gb’ Olugbala gbo, T’o to isura nwon si oke Ahon ko le s’ adun Itunu alafia, Ti okan
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar