
OLORUN lat’ oro d’ ale
1. OLORUN lat’ oro d’ ale, Wakati wo l’ o dun pupo, B’ eyi t’ o pe mi wa ‘do Re Fun adua? 2. Ibukun

1. OLORUN lat’ oro d’ ale, Wakati wo l’ o dun pupo, B’ eyi t’ o pe mi wa ‘do Re Fun adua? 2. Ibukun

1. WA k’ a da m’ awon ore wa Ti nwon ti jere na; N’ ife k’ a f’ okan ba won lo S’ ode

1. GBA alare nwa sinmi, Ti nwon w’odo Re; Gba nwon ko ‘banuje won Wa si ‘waju Re; Gb’eni damu w’alafia Nke p’oruko Re; Gba

1. ADUA didun adua didun, T’o gbe mi lo kuro l’aiye, Lo ‘waju ite Baba mi, Ki nso gbogbo edun mi fun; Nigba ‘banuje at

1. IGBAGBO mi nwo O, Iwo Od’-agutan, Olugbala Jo gbo adua mi, M’ese mi gbogbo lo, K’emi lat’oni lo Si je Tire. 2. Ki ore-ofe

1. TIRE l’ awa Kristi, Titi aiyeraiye, A fe fi gbogbo okan wa Fun O patapata. 2. Ao ro mo O sibe, Pelu itara nla;

1. B’ AYO aiye ti j’ asan to! Didara won ko pe! Ko s’ ayo ti ko l’ ororo, Adun re je ‘dekun. 2. Gbogb’

1. JESU, agbara mi, Iwo l’ aniyan mi, Emi fi igbagbo w’ oke, Iwo l’ O ngb’adua. Jeki nduro O, Ki nle se ife Re,

1. BUKUN ni fun ohun, T’ o de wa po n’nu ‘fe; Idapo awon olufe, Dabi ijo t’ orun. 2. Niwaju ‘te Baba, Li awa

1. B’ENU mi dun bi t’ awon ju, T’ ede mi ta t’ angeli yo; Laisi ife mo dab’ ide, Ti ohun re nhan ni
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar