
IMOLE ojo ‘simi
1. IMOLE ojo ‘simi Je l’ o ku mo wa l’ oju, B’ igbat’ orun iba wo, Fun ajo onigbagbo. 2. B’ imole ti nrekoja,

1. IMOLE ojo ‘simi Je l’ o ku mo wa l’ oju, B’ igbat’ orun iba wo, Fun ajo onigbagbo. 2. B’ imole ti nrekoja,

1. BABA, aniyan at’ eru Le su l’ ojo ola, Sugbon ‘foya ko le wo ‘bi; Tire l’ ojo oni. 2. A k’y’o da okan

1. OLUWA, isimi Re dun; Sugbon t’ oke ju ti aiye lo; Sibe pelu ‘reti ayo Li okan ongbe wa nsare. 2. Ko si are,

1. GBOGB’ ogun orun nro keke, Angeli mu harpu won, Awon mimo nt’ ohun won se Lati josin t’ o l’ ogo; Ojo ‘simi t’

1. EMI wa ba w ape, L’ ojo isimi yi; Laisi Re awa ko le sin, A ko le gb’ adura. 2. Asan li orin

1. ABE, a fe ri o, Ojo ‘simi rere, Gbogbo ose a ma wipe, Iwo o ti pe to? 2. O ko w ape Kristi

1. JESU, a fe pade, L’ ojo Re mimo yi; A si y’ ite Re ka, L’ ojo Re mimo yi; ‘Wo Ore wa orun,

1. OSE, ose rere, Iwo ojo ‘simi; O ye k’ a fi ojo kan, Fun Olorun rere; B’ ojo mi tile m’ ekun wa, Iwo

1. OJO ‘mole l’ eyi, K’ imole wa l’oni; ‘Wo, Orun, ran s’ okunkun wa, K’o si le oru lo. 2. Ojo ‘simi l’eyi, S’

1. EYI l’ ojo Oluwa da, O pe ‘gba na n Tire; K’ orun ko yo, k’ aiye k’ o yo, K’ iyin y’ ite
We promise not to spam you