
IJINLE l’ oro Re, Jesu
1. IJINLE l’ oro Re, Jesu, Tani le tumo re? Tani gbon to! tani mo to! Tal’ oye re po to! 2. Tani le si

1. IJINLE l’ oro Re, Jesu, Tani le tumo re? Tani gbon to! tani mo to! Tal’ oye re po to! 2. Tani le si

1. OWO l’ eni ororo Re, L’ ojise oro mimo Re Ipo eni owo l’ o wa, Jek a f’ iyin at’ ola fun. 2.

1. KRIST’, nin’ ogba Eden, L’ a gbe ti ri r’ ase yi, Ase Tire, P’ o ye f’ eni meji Ki nwon jo ma

1. NI Kanani ti Galili, Nib’ ase ‘gbeyawo, Jesu f’ ara Re han nibe, Pel’ awon ‘mo-ehin. 2. Jesu masai f’ ara Re han Nibi

1. IRE t’ a su ni Eden’, N’ igbeyawo ‘kini, Ibukun t’ a bukun won O wa sibesibe. 2. Sibe titi di oni, N’ igbeyawo

1. JESU f’ ara han nitoto, Nibi ase ‘yawo; Oluwa, awa be O, wa F’ ara re han nihin. 2. Fi ibukun Re fun awon

1. SIMI le Oluwa -e gbo Orin duru orun – Simi le ife ailopin, Si duro je, 2. Simi, iwo oko t’ o gba Iyawo

1. JESU f’ eje Re raw a, E jek’ a sunm’ Olorun; Opo nsina yi wa ka; K’ anu mu wag badura, – Pe ki

1. WA, Oluwa, l’ anu tun wa, Pelu ‘pa ‘p’ okan da, Ongbe ojo np’ oko Sion, Masai ro s’ ori re. 2. Okan wa

1. GBO l’ or’ ite Re, Alade, F’ oniruru ‘bukun ranse, B’ awon omo Re ti nwa O, Gb’ adura t’ oro Re ko ni.
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar