
EFUN ‘pe na kikan
1. EFUN ‘pe na kikan, Ipe ihinrere, K’ o dun ja ‘ke ja ‘do, L’ eti gbogbo eda; Refrain Odun idasile ti de, Pada, elese,

1. EFUN ‘pe na kikan, Ipe ihinrere, K’ o dun ja ‘ke ja ‘do, L’ eti gbogbo eda; Refrain Odun idasile ti de, Pada, elese,

1. IRANSE Oluwa! E duro nid’ ise; E toju oro Re mimo, E ma sona Re sa, 2. Je k’ imole nyin tan, E tun

1. MA sise lo, mase sare, Fi ayo sise Baba re; Bayi ni Jesu se l’ aiye Ko ha ye k’ awa ko se be?

1. JESU y’o joba ni gbogbo Ibit’ a ba le ri orun; ‘Joba Re y’o tan kakiri, ‘Joba Re ki o n’ ipekun. 2. On

1. GBO! Orin ti Jubili, O dabi sisan ara; Tabi bi kikun okun, Gbat’ igbi re ba nlu ‘le Halleluya! Olorun Olodumare joba; Halleluya! K’

1. FUNRUGBIN l’ owuro, Ma simi tit’ ale; F’ eru on ‘yemeji sile Ma fon s’ ibi gbogbo. 2. ‘Wo ko mo ‘yi ti nhu,

1. ORO die fun Jesu; Ore otito ni; Wa tu okan wa ninu Ohun t’o se fun o. Oro die fun Jesu, Yio gba wa

1. LO kede igbala Jesu Gbogbo enyin onigbagbo Fun ‘rugbin Sharon ka gbogbo, Orile ede aiye yi. 2. Yio f’ agbala ‘na yi o ka

1. AGOGO ihinrere Nlu lat’ ilu de ‘lu ‘Bukun ati ‘gbala ofe, Ni nwon fun o at’ emi, Olorun f’ araiye T’ O fi Omo

1. FUN ‘rugbin l’ owuro, irugbin inu ‘re Funrugbin l’ osan gan, ati ni ale Duro de ikore ati ‘gba ikojo A o f’ ayo
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar