
ODUN miran ti koja
1. ODUN miran ti koja, Wawa l’ akoko na lo, Ninu eyit’ a wa yi, Yio se arimo opo; Anu l’ O fid a wa

1. ODUN miran ti koja, Wawa l’ akoko na lo, Ninu eyit’ a wa yi, Yio se arimo opo; Anu l’ O fid a wa

1. ALAKOSO ti orun, Alanu at’ Ologbon; Igba mi mbe l’ owo Re, Opin gbogbo l’ ase Re. 2. Ase Re l’ o da aiye

1. OLUWA alafia wa L’ O pase t’ odun yipo; Awa omo Re wa dupe F’ odun titun t’ a bere. Yin Oluwa! Oba nla

1. OLORUN t’ odun tr’ o koja, Iret’ eyi ti mbo; Ib’ isadi wa ni iji, At’ ile wa lailai. 2. Labe ojiji ite Re

1. B’ ORUN l’ aiduro ti rin, La odun ti o lo ja Be l’ opo ti d’ opin won A ki o si ri

1. OLUWA at’ ‘igbala wa, L’ o ko wa jo l’ ale oni, Je ka gbe Ebeneser ro; Odun t’ a ti la koja yi,

1. NI akoko ipinya, Jeki a fi ara wa, S’ abe oju at’ okan, Ore korikosun wa. 2. Jesu gbo adura wa, ‘Wo ti nso

1. AO ha pade l’ eti odo, T’ ese angeli ti te, ‘T o mo gara bi kristali, Leba ite Olorun? Ao ha pade l’

1. K’ OLORUN so o, k’ a tun pade Ki imoran Re gbe o ro, K’ O ka o mo agutan Re, K’ Olorun so

1. NIHIN l’ awa nje ‘rora, Nihin ni a ma pinya, L’ orun ko si ‘pinya, A! bi yio ti dun to! Dun to, dun
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar