
ALABUKUN n’nu Jesu
1. ALABUKUN n’nu Jesu Ni awon om’ Olorun Ti a fie je Re ra Lati ‘nu iku s’ iye; A ba je ka wa mo

1. ALABUKUN n’nu Jesu Ni awon om’ Olorun Ti a fie je Re ra Lati ‘nu iku s’ iye; A ba je ka wa mo

1. AKO n’ ibugbe kan nihin, Eyi ba elese n’nu je; Ko ye k’ enia mimo kanu, ‘Tori nwon nfe ‘simi t’ orun. 2. A

1. AWON mimo! Ija nwon pin, Nwon segun aiye nikehin, Nwon ko fe ohun ija mo; Nwon da won si ese Jesu; Awon mimo! Eni

1. TAL’ awon wonyi b’ iranwo, Niwaju ‘te Olorun? Gbogbo nwon de ade wura, Egbe ogo wo l’ eyi? Gbo! nwon nko, Alleluya, Nwon nf’

1. EGBEGBERUN aimoye Nwon wo aso ala, Ogun awon t’a rapada Nwon kun ‘bi ‘mole naa; Ija won pelu ese At’ iku ti pari; E

1. OPO ikan omi, Yanrin kekeke; Wonyi l’ o d’ okun nla At’ ile aiye. 2. Iseju wa kokan, Ti a ko kasi, L’ o

1. MASE huwa ese, Ma soro ese; Omo Jesu l’ e se, Omo Oluwa. 2. Krist je oninure, At’ eni mimo; Be l’ awon omo

1. GBATI Samueli ji To ‘igb’ ohun Eleda Ni gbolohun kokan, Ayo re ti po to Ibukun ni f’ omo t’ o ri Olorun nitosi

1. OJ’ oni lo Jesu Baba, Boju Re w’ emi omo Re. 2. ‘Wo Imole, Se ‘toju mi; Tan imole Re yi mi ka. 3.

1. JESU Onirele, Omo Olorun: Alanu, Olufe, Gbo ‘gbe omode. 2. Fi ese wa jin wa Si da wa n’ ide; Fo gbogbo orisa, Ti
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar