
JEJE, lai si ariwo
1. JEJE, lai si ariwo, Jeje li orun nran, Gbat’ o bay o n’ ila re, Eda le w’ oju re; B’ o si ti

1. JEJE, lai si ariwo, Jeje li orun nran, Gbat’ o bay o n’ ila re, Eda le w’ oju re; B’ o si ti

1. OLUWA, iji nfe s’ oke! Igbi omi nru s’ oke! Oju orun pelu su dudu, ‘Ranlowo ko si n’ tosi; ‘Wo ko bere bi

1. OJO ibukun yio sir o!” Eyi n’ ileri ife; A o ni itura didun Lat’ odo Olugbala Ojo ibukun! Ojo ibukun l’ a nfe;

1. GBA Jesu ba de lati pin ere, B’ o j’ osan tabi l’ oru, Y’o ha ri wa nibit’ a gbe ns’ ona, Pel’

1. LAB’ agbelebu Jesu Mo fe lati duro, – Oji apata titobi Ninu ile are, Ibugbe ninu aginju, Ib’ isimi l’ ona, Kuro n’n’ oru

1. FUN mi n’ iwa pele, Okan tutu; Ifarabale bi T’ Oluwa mi; Irele on suru At’ opo oiyonu, Ninu ohun gbogbo Ki njo Jesu.

1. L’ AYO l’ a ro t’ ore-ofe Alufa wa l’ oke; Okan Re kun fun iyonu, Aiya Re ntan fun ‘fe. 2. Nipa ibakedun

1. ORE-OFE! Ohun Adun ni l’ eti wa; Gbongbon re yio gba orun kan, Aiye o gbo pelu. Ore-ofe sa, N’ igbekele mi; Jesu-ku fun

1. ONISEGUN nla wa nihin, Jesu abanidaro; Oro Re mu ni l’ ara da, A, gbo ohun ti Jesu! Iro didun l’ orin Seraf’, Oruko

1. KO to k’ awon mimo beru, Ki nwon so ‘reti nu; ‘Gba nwon ko reti ‘ranwo Re, Olugbala yio de. 2. Nigbati Abram mu
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar