
NGO ha ku ni owo ofo
1. NGO ha ku ni owo ofo, Ki mba oluwa mi be Ko ti fun u n’ise ojo kan, Ikogun fun On ko si. Refrain

1. NGO ha ku ni owo ofo, Ki mba oluwa mi be Ko ti fun u n’ise ojo kan, Ikogun fun On ko si. Refrain

1. NGO korin itan ‘yanu na, Ti Jesu t’ o ku fun mi, B’ On ti fi ‘le ogo sile, F’agbelebu Kalfari. Refrain A ngo

1. MASE f’oiya ohun t’ o le de, Olorun y’o so o; Duro labe iye Re, Olorun y’o so o. Refrain Olorun y’o so o,

1. O TI to Jesu f’ agbara ‘wenumo? A we o nin’ ej Odagutan? Iwo ha ngbekele ore-ofe Re? A we o nin’ ej Odagutan?

1. WO kakiri f’ enit’ o s’ alaini, R’ enia lowo loni! Bi ‘ranlowo na si tile kere, R’ enia lowo loni! Refrain R’ enia

1. NKO le sai gb’ ona agbelebu lo ‘le, Ko tun si ona miran; Nko le ri ilekun imole na Bi nko si l’ ona

1. NIGBA igbi aiye ba dide si o, T’ okan re baje pe gbogbo nkan segbe, Siro ibukun re, ka won lokokan, Enu y’o ya

1. ENYIN ero, nibo l’e nlo T’ enyin t’ opa lowo nyin?” A nrin ajo mimo kan lo, Nipa ase Oba wa, Lori oke on

1. OHUN ipe kan ti, oke petele wa, S’ olotito, ‘lotito, ‘lotito si Krist, Oke gba orin na, gege b’o ti ndun lo, T’ olotito,
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar