
EMI, Olore ofe
1. EMI, Olore ofe, Tan ‘mole Re s’ okan mi; M’ eru ebi mi kuro; F’ ife Re orun kun mi. 2. Je kin mo

1. EMI, Olore ofe, Tan ‘mole Re s’ okan mi; M’ eru ebi mi kuro; F’ ife Re orun kun mi. 2. Je kin mo

1. WA Emi Mimo, wa, Pelu ipa t’ orun, Si ran ninu anu Re nla Sor’ okan okun wa. 2. Yo okan lile yi; Te

1. OLURAPADA wa, k’ On to Dagbere ikehin, O fi Olutunu fun mi, Ti mba wa g be. 2. O wa ni awo adada, O

1. WA, Emi ‘re, ‘Dada orun Pelu itunu lat’ oke; S’ alabo at’ Oluto wa, To ero at’ isise wa. 2. F’ imole otito han

1. EMI Mimo, ‘Dada orun, Wa li agbara Re; K’ o da ina ife mimo, Si okan tutu wa. 2. Wo, b’ a ti nrapala

1. EMI orun, gb’ adura wa, Wa gbe ‘nu ile yi, Sokale pel’ agbara Re, Wa, Emi Mimo wa. 2. Wa b’ imole, si fihan

1. EMI anu, oto, ife, Ran agbara Re t’ oke wa; Mu iyanu ojo oni, De opin akoko gbogbo. 2. Ki gbogbo orile-ede, Ko orin

1. OGO fun Olorun Baba, Ogo f’ Olorun Omo, Ogo fun Olorun Emi, Jehofa, Metalokan; Ogo, ogo. B’ aiyeraiye ti nkoja. 2. Ogo fun Enit’

1. A F’ iyin aiku fun ‘Fe Olorun Baba, Fun itunu t’ aiye, At’ ireti t’ orun: O ran ‘Mo Re aiyeraiye Lati ku fun

1. F’ ORUK’ Olorun loke, T’ O l’ agbara at’ ola, Olorun ibi gbogbo, N’ iyin ati ogo wa. 2. F’ oruko Krist’ Oluwa, Om’
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar