
OLORUN ti fi Jesu se
1. OLORUN ti fi Jesu se Etutu fun ese; On na l’ okan mi duro ti, Ninu igbagbo mi, 2. Olorun si ni iyonu Si

1. OLORUN ti fi Jesu se Etutu fun ese; On na l’ okan mi duro ti, Ninu igbagbo mi, 2. Olorun si ni iyonu Si

1. OLUWA, alaimo l’ emi, Ninu ese l’ a gbe bi mi, Eniti mo se lara re L’ o fi ese ba aiye je. 2.

1. ENI ‘subu se le Mo loju Olorun, Bi O ba tele pipe wa Ao subu lab’ egbe. 2. Bi O ba fi oju Mimo

1. OLUWA, bawo l’ okan mi Ti bale lekan ri; Mo wa laye laisi ofin, Mo seb’ ese mi ku. 2. Ireti duro sinsin, Sugbon

1. ASAN n’ ireti t’ enia ko Le ori ise won: A bi won pel’ okan eri, Ebi si n’ iwa won. 2. Ki ju,

1. GBAT’ emi re ba fo lo, T’ iku ba siji bo o; ‘Gbati sa re ba pari, Elese n’ bo l’ o yo si?

1. NIBO n’ isimi wa Fun okan alare? Asan ni lati w’ aiye ka, Lati wa ‘le okun. 2. Aiye ko le fun ni Layo

1. LONI ni Jesu pe! Asako wa; A! okan okunkun Ma kiri mo. 2. Loni ni Jesu pe, Tetilele: Ni ile owo yi, Wole, Jesu.

1. ELESE kil’ o ni t’ o Jo ayo onigbagbo? Pelu ododo riro, Ona re dun to ti ‘wa 2. Onisegun t’ o daju Ha

1. “A YE si mbe!” ile Odagutan, Ewa ogo re npe o pe, “Ma bo”, Wole, wole, wole nisisiyi. 2. Ojo lo tan, orun si
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar