
BABA orun, ti ife Re
1. BABA orun, ti ife Re B’ okan wa, wa irapada, A teriba niwaju Re, Jo fun wa n’ idariji Re. 2. Om’ Olorun Alagbara,

1. BABA orun, ti ife Re B’ okan wa, wa irapada, A teriba niwaju Re, Jo fun wa n’ idariji Re. 2. Om’ Olorun Alagbara,

1. BAWO ni awon ewe wa, Y’o ti ma sora won; Bikose “nipa ‘kiyesi, Gege bi oro Re,” 2. ‘Gba oro na wo ‘nu okan;

1. BIBEL’ iwe aiyeraiye Tani le ridi re? Tani le so idide re? Tani le m’ opin re? 2. Asiri olodumare; Iko Oba orun Ida

1. IWO Oro Olorun, Ogbon at’ oke wa, Oto ti ki ‘yipada, Imole aiye wa; Awa yin O fun ‘mole, T’ inu iwe mimo; Fitila

1. IWE kan wa ti kika ra, Ko soro fun enia, Ogbon ti awon t’o ka nfe, Ni okan ti o mo. 2. Ise gbogbo

1. TORI Mi at’ ihinrere, E lo so t’ Irapada; Awon onse Re nke “Amin” Tire ni gbogbo ogo; Nwon nso t’ibi tiya t’iku, Ife

1. IWO oro t’o tobi, Ninu eyit ‘a ri, Ileri ati sise Awamaridi ni: Nigba ekun at’ ayo, Idanwo at’ eru, Mo gbo Jesu wipe,

1. JESU, Oba nla ni Sion, ‘Wo ni yio j’ amona wa; Ase Re li a gbekele, Iwo nikan l’ ao tele. 2. Bi apere

1. JESU mo bg’ agbelebu mi, Ki nle ma to O lehin; Otosi at’ eni egan, ‘Wo l’ ohun gbogbo fun mi; Bi ini mi

1. ENI ‘rele, t’ o nwa ‘gbala Nip’ eje Od’-agutan, E gbo ohun isipaya, Erin ‘na ti Jesu rin.s 2. Gbo Olugbala t’ O npe
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar