
OLUWA, mo gbo pe Iwo
1. OLUWA, mo gbo pe Iwo Nro ojo ‘bukun kiri; Itunu fun okan are, Ro ojo re s’ ori mi. An’ emi! Ro ojo re

1. OLUWA, mo gbo pe Iwo Nro ojo ‘bukun kiri; Itunu fun okan are, Ro ojo re s’ ori mi. An’ emi! Ro ojo re

1. MA koja mi, Olugbala, Gbo adura mi; ‘Gbat’ Iwo ba np’ elomiran, Mase koja mi! Jesu! Jesu! Gbo adura mi, Gbat’ Iwo ba np’

1. WO ‘le ‘wo enit’ a bukun, O ki tun s’ alajo; A fi gbogbo okan gba o, ‘Wo arakunrin wa. 2. Owo ‘dapo, at’

1. ARA n’nu Krist’, nitori Re, A fi t’ okantokan gba o; K’ a le jumo je ayo ti Ko s’ en’ti fun ni lehin

1. WO ‘le, ‘wo alabukunfun; Wa l’ oruko Jesu owon; A f’ ohun kan ke, “Ma wole,” A ro pe Jesu kio pelu. 2. Ayo

1. ENYIN enia Olorun, Mo ti kiri aiye ka, To ‘pa ese on ‘kanu, Nko r’ itunu n’ ibikan. 2. Okan mi pada sin yin,

1. JESU, ‘ Wo Olus’-agutan, Pa agbo Re kekere mo; Gb’ awon agutan Re wonyi, Ma jekii nwon ko gbo lai. 2. Dabobo nwon labe

1. JI ‘se Re nde Jesu! Fi agbara Re han! Fo ‘hun t’ o le j’ oku dide Je k’ enia Re gbo. 2. Ji

1. MA f’ ara fun ‘danwo, nitor’ ese ni Isegun kan yio f’ ipa miran fun o Ma ja bi okunrin, segun ibinu Ma tejumo

1. A, JESU Alabukun, A m’ orin ayo wa, Ohun at’ okan ‘pe wa L’ ayo l’ a gbe si O; O ga, O si
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar