
TO nwon, Baba si O
1. TO nwon, Baba si O, To nwon si O; Awon omo wonyi Ti O fun ni, Nipa ‘fe Re orun, To nwon, Baba si

1. TO nwon, Baba si O, To nwon si O; Awon omo wonyi Ti O fun ni, Nipa ‘fe Re orun, To nwon, Baba si

1. OLUWA sokale, Bukun awon ‘mo ma, Laipe, ki ife won le te Si ore-ofe Re. 2. B’ o ti je ‘fe wa to Lati

1. E DIDE ki a si lorin, K’ a yin Oluwa wa, K’ a si dupe li owo Re, F’ anfani idasi. 2. E dide

1. OSE, ose t’ a nreti A ki o pe “Ma wole,” Iwo ni idunnu wa, A kio s’ ole ninu re. 2. A wa

1. LEHIN ‘jo mefa t’ O sise, O simi ni ijo keje, O pase fun wa k’ a se be, Ki a si pa ojo

1. JESU Oba, a pari eko wa, Ma jeki Esu sa je l’ okan wa. 2. Jesu Oba, a s’ ope lowo Re, T’ O

1. K AWA to pari eko wa, Awa f’ iyin fun O; ‘Tori ojo Re mimo yi, Jesu Ore ewe. 2. Gbin oro Re si

1. MO fe ki ndabi Jesu, Ninu iwa pele; Ko s’ enit’ o gboro ‘binu L’ enu Re lekan ri. 2. Mo fe ki ndabi

1. BI osun gbege eti ‘do, Tutu minimini; B’ igbo dudu eti omi, B’ itanna ipa ‘do. 2. Be l’ omo na yio dagba, Ti

1. ILE-EKO ojo ‘sinmi, A, mo ti fe O to! Inu mi dun mo daraya Lati yo ayo re 2. Ile-eko ojo ‘sinmi, Oore re
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar