
K’ ORE-ofe Krist’ Oluwa
1. K’ ORE-ofe Krist’ Oluwa, Ife Baba ailopin, Oju rere Emi Mimo K’ o t’ oke ba lori wa. 2. Bayi l’ a le wa

1. K’ ORE-ofe Krist’ Oluwa, Ife Baba ailopin, Oju rere Emi Mimo K’ o t’ oke ba lori wa. 2. Bayi l’ a le wa

1. OLORUN l’ odo eniti ‘Toju ife ti nwa, Iforiti gbagbo ‘reti, Ro ‘jo won lat’ oke. 2. Pin won fun olukuluku, Bi won ti

1. JESU awa nwo O fun ‘Wosan alailera yi ‘Wo lo ti se anu nla, F’ abiirun let’ adagun. 2. Ko s’ onisegun bi Re;

1. JESU ‘ wo Onisegun nla, T’ olokunrun nf’ ailera mo, Nigba aisan at’ irora, O se dida ara fun won. 2. Afoju, aro, alaisan,

1. MO gbeke mi le O, Lori ibusun mi, Gba mi lowo irora mi, Ki O si wo mi san. 2. Ko s’ elomiran mo,

1. ISE re Oluwa, Awamaridi ni, Ohun gbogbo ni mu ‘re wa, F’ eni to se ‘fe Re. 2. O ri ailera mi, Aisan at’

1. B’ ODO ti nyara san lo, Li ona gboro re, Ti omi re nja titi, T’ o nsare lo s’ okun, Beni aiye wan

1. KO mi ni iwon ojo mi, Iwo Eleda mi; Mo fe w’ ona toro aiye, Ki nmo ailera mi. 2. Ese kan pere ni

1. OLORUN lat’ irandiran, ‘Wo n’ isimi at’ abo wa, K’ a to da orun at’ aiye, Giga ni ife Re l’ oke. 2. O

1. LAB’ ese, ati l’ oke wa, Ni ikilo tin dun, Oku aimo ‘ye sun n’nu ‘le, Orun si wa l’ oke. 2. Iku gun
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar