
LAT’ ori pepe okan wa
1. LAT’ ori pepe okan wa , Je ki orun dide; Oluwa ma sai ba war u Ebo asale wa. 2. Iseju at’ opo anu

1. LAT’ ori pepe okan wa , Je ki orun dide; Oluwa ma sai ba war u Ebo asale wa. 2. Iseju at’ opo anu

1. K’ A to sun, Olugbala wa, Fun wa n’ ibukun ale; A jewo ese wa fun O, Iwo l’o le gba wa la. Bi

1. OJO oni lo tan, Oru sunmole: Okunkun ti de na, Ile si ti su. 2. Okunkun bo ile, Awon ‘rawo yo; Eranko at’ eiye,

1. WO Imole! larin okun aiye, Ma sin mi lo. Okunkun su, mo si jina s’ ile, Ma sin mi lo. To ‘sise mi: bi

1. ERO didun kan nso S’ okan mi firifiri, Mo sunmo ‘le mi l’ oni, Ju bi mo ti sunmo ri. 2. Mo sunmo, ‘te

1. BABA, a tun pade l’ oko Jesu, A si wa teriba lab’ ese Re; Si O l’ a tun fe gb’ ohun wa s’

1. IWO imole okan mi, Li odo Re oru ko si, Ki kuku aiye ma bo O Kuro l’ oju iranse Re. 2. Nigbat’ orun

1. OLUWA, ojo t’ O fun wa pin Okunkun si de l’ ase Re ‘Wo l’ a korin owuro wa si, Iyin Re y’o m’ale

1. L’ OJU ale, ‘gbat’ orun wo, Nwon gbe abirun wodo Re: Oniruru ni aisan won, Sugbon nwon f’ayo lo le won 2. Jesu a

1. IFE Re da wa si loni, L’ are a si dubule; Ma so wa n’ idake orun, K’ ota ma yow a l’enu: Jesu,
We promise not to spam you
Support the Yoruba Baptist Hymns project.
Give via Selar:
Give a Gift on Selar